Onílè mo júbà o
Ìbà Òrisà
Ìbà Onílè
E pa 'gbo o
E pa 'gbo wa tan ' gala
A tan 'gala nilè kò rò ó
E pa 'gbo erú jéjé
Tóto n ilè kò rò ó
Aye kuru
Onílè Kéré
Onílè Kéré l' odò
Onílè Kéré o
Onílè kú ewu o
E o ina (n)
Kini pàwòdì
Assinar:
Postar comentários (Atom)
Nenhum comentário:
Postar um comentário