Ádufé o
E pé yá dòde
Àfufé o
E pè yá dòde
Ìyá o'runmalè yo
Ìyá o'runmalè yo
Ìyá omi má l' óde odara
Ìyá omi ma fantilé omo (n)
E pè ja ni ma roba Ìyá wa dode
Àdufé o
Àdufé sadere
O f' aran si
Àdufé sadere
O f' aran si
Ìyá omo dundum Àwòyò
Àdufé sadere
O f' aran si
Àdufé ni mo gbà
Sun ' alè
Àdufé ni mo gbà
Sun ' alè
O yio rò jo le npe
Àdufé ni mo gbá
Sun ' alè
Yemonja wa ko
Yemonja wa ko
Àgò pa imò (n)
Àgò pa imò (n)
Àdufé ko je máa o
Aro sí wa le o
Béré kíni
Kíni làarin
Oní Dàda
Àgò làarin
Dàda má sokún mó (n)
Dàda má sokún mo (n)
E ru Isele be l' òrun
Dàda fún mi l' ówó
Ká su máa rin
Báyànni gidigi
Báyànni olá
Báyànni gidigi
Báyànni adé (owó)
F' urà jinà
F' urà jinàF' urà jinà
Ara lo si sàjo
F' urà jinàF' urà jinà
F' urà jinà
Ata l' òko níbe
Óràín a l' óde o
Bara eni ja
Enia roko
Oní máa
Ni mo eje
Bara eni ja
Enia roko
Oníka re l' usaki
Obalube kereje
Kereje le bumore
Kereje agutan
Itetu pade wa l' óna
Oníka si re le
Ibo si Òràín
A l' óde o
Bara eni ja
Enia roko
Oba séré
La fèhintin Oba
Oba Séré
La fèhintin Oba
Oba nwa ' iyé bè l ' òrun
Oba séré La fèhintin
Oba nwa ' iyé bè l ' órun
Oba séré La fèhintin
Oba kère kére wa ' do
Òsi e r' ole
Ìyá l' ódò Mase
E ko ke re l' anú
S' oko ìyàgba
Ìyá l' ódò Mase
Aira òjo
Mo pé re' se
A mo pè re' se
A nwa' wúre
A nwa òrisá
Obalube oba l' adó
Oba l' adó rí só
Fún àiyè
Oba l' adó rí só
Fún àiyé
Oba l' adó rí só
Fún àiyé
O lo ti re
Lo ti pa
E tàbi esin
O lo ti re
Lo ti pa
O pé o dòde
Irú wo
Ko máa bo níbo
Alàáfin òrisà
Alàdó
Ko máa bo níbo
E kò pa
Irú wo
Ko máa bo níbo
Alàáfin òrisà
Alàdó
E kò pa nije
Lésé e ko ina
Eru jéjé eru jéjé
Lésé e ko ina (n)
L' óke odó
Lésé e ko ina (n)
Eru óke odó
Lésé e ko ina (n)
Eru jéjé eru jéjé
Lésé e ko ina (n)
Eru jéjé
Oba s' oro 'ro
E ja gbe ko mbere
E ko ima e ko imò (n)
E ja gbe ko mbere
E ko imò (n)
E ko pa nije
E ja gbe ko nbere
E ko ima e ko imò (n)
E ja gbe ko mbere
E ko imò (n)
E kò pa
Oba mi ke s' oro
So mbe
Oba s' oro 'ro
Oba mi ke s' oro
So mbe
Oba s' oro 'ro
Assinar:
Postar comentários (Atom)
agbo sango ase opo afonja exelente
ResponderExcluir